Ìfẹ́ yìí ga jù, Regina Daniels ya ọkọ rẹ̀ lẹ́nu

Regina ati Nwoko

 

 

Oko Regina Daniels olowo okowo tabua, omooba Ned Nwoko, ti mo riri bi iyawo re owon se ya a lenu ni ojo ibi re, ti o si gba wi pe oun kii se eni ti o ma n se ojo ibi.

Olowo tabua eni ti o pe omo odun mejile-ni-ogota ni ojo kokanle-ni-ogun osu kejila, ti Regina Daniels si se afihan pe oun n gbaradi lati ya oko oun lenu pelu ayeye ojo ibi ni nnkan bii ojo meta saaju ojo naa.

Sibesibe, ayeye naa je aseyori ti opolopo ebi ati molebi si ye ojo naa si, Regina Daniels fi fonran bi ayeye naa se lo sowo si ori ayelujara bi o se dupe lowo awon ti o gbo ti won si wa.

Ewe, Regina Daniels se apejuwe oko re ni ona ti o wuni lori julo ninu fonran naa ti o si fi kun un pe inu oun dun lati je iyawo omooba Ned.

Ned naa soro, o so bi inu re ti se dun to lati je oko Ragina Daniels pelu. O tesiwaju lati se imoriri ohun ti aya re ati oserebinrin Nollywood naa se, ni bi o se so pe oun nife ipa ati ifarasin re fun ise ti o yan laayo. O soro siwaju si i, o fi kun un pe oun kii se eni ti o n se ojo ibi rara, be ni ajoyo eyi je ohun iyalenu gbaa fun un. Ned Nwoko so pe:

“Mi o kii se ojo ibi, mi o se e ri. Eyi je iyalenu nla gbaa fun mi.”

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here