Mary Fagbohun
Obinrin nifiimu onirawo kan, Nkechi Blessing, ti so faye bi ohun ti se se iwuri fun awon elomiran lati gbagbo ninu ife leekan si, o si ro awon akegbe re lati wa iha ninu iha ara won.
O lo si ori opo Instagram lati fihan pe opo eniyan ni o ti tara re ni iwuri lati gba ara won laaye lati ni ife leekan si i.
Oserebinrin Nollywood eni ti o wa ninu ibasepo kan pelu odomokunrin kan ti so pe ki awon eniyan mase lero pe oun n se eyi lati fi gapa.
Nkechi wa ro awon ilumooka lati sokale lati ori esin igberaga ti won gun, ki won si wa ife lawari; enikan yoo mu inu won dun
O k o wi pe: TI MU KI OPOLOPO ENIYAN GBAGBO NINU IFE LATI EYIN WA…E MASE RO WI PE MO FI ORO YII LEDE LATI GAPA ..RARA!! E GBO EYIN ILUMOOKA E WA IFE KI INU LE E DUN…E SOKALE LATI ORI ESIN IGBERAGA YIN, KO SI OHUN TI O WA NIBE..IRE