Mo ta ilẹ̀ Banana Island láti lọ sí Eko Atlantic Estate

Gbaju-gbaja olorin, David Adeleke ti gbogbo eniyan mọ si Davido lo n salaye yii lori opo ayelujara rẹ.
Davido ni oun ri ara oun bi ẹni to lagbara ju Banana Island lọ, eyi lo jẹ ki oun ta ilẹ naa ni biliọnu meji ati miliọnu meji naira.
“Mo ra ti Eko Atlantic ni biliọnu meje, mo si maa na to biliọnu ogun si akanse ise naa ko to le pari. Mo ni igbagbọ pe o maa pari ni ọdun to n bọ.” Alaye rẹ naa niyẹn.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here