Iṣẹ́ Èṣù ló jẹ́ kí n máa fi ìmúra bíi Mùsùlùmí jalè – Ìyá ìjọ
Agọ ọlọpaa ni Ado Ekiti ni ipinlẹ Ado ni abilekọ yii ti n rawọ ẹbẹ si ọmọ Naijiria.
O ni ki wọn jọwọ fori ji oun, o ni isẹ Esu ati ọna atijẹ lo jẹ ki oun maa dọgbọn bii ẹlẹsin Musulumi jale.
E wo fidio iya naa –









