Mo kó milionu mẹ́wàá naira fún ipa kan nínú fíìmù  – Chinwetalu Agu

Mo kó milionu mẹ́wàá naira fún ipa kan nínú fíìmù  – Chinwetalu Agu

 

Ogbontarigi osere tiata, Chinwetalu Agu ti seranti bi o se ko milionu mewaa naira fun adehun ibasisepo lati odo olowo tabua, Mike Adenuga, lati ko ipa kan ninu fiimu.

 

O so pe nigba olowo tabua naa fun oun ni anfaani yi, oun ko tile tii ni milionu kan naira ri saaju sugbon oun duro lori pe ki o owo naa pe oke kan milionu naira.

 

Akoni osere tiata naa so pe Adenuga leyin naa gba, o si fun oun ni oke kan milionu naira leyin ti oun hale lati kuro nibe.

 

Agu safihan eyi ninu ijiroro kan pelu gbajumo olootu eto, Chude Jideonwo.

 

O ni, “Oloye Mike Adenuga so pe, ‘nnkan ti mo ni fun o ni milionu mewaa naira.’ Mi o tii ri milionu kan naira ri nigba to fun mi ni idiyele milionu mewaa naira sugbon mo ko o. Mo so pe, ‘ti kii ba se oke kan milionu naira, gbagbe re.’

 

“O duro, Emi naa si duro. Nitori naa, mo dibon bii pe mo fe maa lo, mo si so pe, ‘funmi ni owo ki n pada si Enugu. Bi oko irinna oju ofurufu kan ba wa, ba mi wa aaye ninu won ki n si maa lo jeje.’

 

“Won gba pe mi o sere rara nigba ti mo dide. Oloye Mike Adenuga so pe ‘jokoo.’ O si so pe ki won gbe iwe wa fun mi ki n si bowoluu. Won gbe e wa mo si se bee.

 

“Lati igba naa ni ijo uhuru ti bere. Mo se e ni ona to ye ninu ofiisi naa. Mi o fe ki won mo pe oke kan milionu naira je adehun ibasisepo ti owo re po [fun mi]. Sugbon o je ohun iyanu [si mi] ni igba naa.”

 

‘Padà, mi ò sí nílé’ – Davido 

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here