MỌ ILÈ̩ AFRIKA

Agbeniyi Edaoto
Ile Gambia je ilu kekere ni ile adulawo Afrika. Gbogbo aala ti ilu yi ni je pelu ile Senegal nikan soso ni. Orisirisi igba ojo ni o wa ninu Gambia nikan soso. Awon eranko igbo ti ko fi bee si mo si wa nil u yii bayi, sibe awon eran igbo bii obo, Erinmi, ati awon eye ti ko fi bee si ni ilu miran po ni ile yii. Awo-tun-wo ni Kiang West National Park ati Bao Bolong Wetland Reserve je.
 
Banjul ni olu ilu Gambi, Gambian Dalasi si ni owo ti won nna ni ile yii, owo yii na lagbara die. O din die ni milionu meje eeyan ton ngbe ilu yii, 1.849 million (2013) World Bank.
 Awon opo ibi igbafe lo wa ni ile yii ti eeyan ti lee gbadun ara re, bii Kololi Serekunda Bakau Brikama Gambia RiverGambia National MuseumKachikally Museum, Kunta Kinteh IslandAbuko Nature Reserve. Gege bii omo Naijiria eeyan ko nilo lati ni iwe ase irina(VISA) kii eeyan to lo si Gambia nitori omo egbe ajo ECOWAS jo ni gbogbo wa.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here