Sowore padà sí ọgbà ẹ̀wọ̀n Kuje

Ile-ẹjọ to fikalẹ si oluulu Naijiria ni Abuja ti da gbaju-gbaja ajafẹtọọ-ọmọniyan, Omoyele Sowore pada si ọgba ẹwọn Kuje.
Ọgba ẹwọn yii wa lara ọgba ẹwọn to lagbara, to ni aabo ni orileede yii.
Ibẹ ni ile-ẹjọ da Sowore pada si lori ẹsun ibani-lorukọ jẹ. Oun ni o pe Aare Tinubu ni ọdaran lori ẹrọ ayelujara.
Eyi lo faa ti awọn agbofinro se muu pe ki o wa salaye awọn iwa ọdaran ti Aare ti wu ti awọn asiri naa si wa lọwọ rẹ.
Idajọ tun di ọjọ kẹrinlelogun osu kẹfa ọdun 2026 yii.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here