Wọ́n dún’kokò mọ́ mi lórí fíìmù tuntun nípa olùsọ́ agbo ẹran — Chloe Coko

Wọ́n dún’kokò mọ́ mi lórí fíìmù tuntun nípa olùsọ́ agbo ẹran — Chloe Coko

 

Mary Fágbohùn

 

Agberejade kan, Chloe Toka-McBaror, ti a mo si Chloe Coko, ti so pe oun ri opolopo ihale isekupa lati odo awon ti oun ko mo lori fiimu tuntun ti o pe akole re ni, ‘Herdsmen (Oluso agbo eran)’.

 

Ninu oro to fi ranse si Saturday Beats, o ni moriya oun gboogi kan lati se agbejade fiimu naa ni lati safihan iro to wa leyin iwa olosa awon iha ariwa Naijiria.

 

O wi pe, “Sise agbejade fiimu yi se okunfa ihale isekupa ati ikilo lati odo ti mi o mo, eyi to bere nigba ti a si n ya fiimu naa, titi di ose yi.  Iwuri to wa leyin fiimu naa ni lati tan imole si isekupani lati owo awon oluso agbo eran ni orile ede yi.”

 

Nigba to n soro lori ohun to mu ki fiimu naa da yato, agberejade naa wi pe, “Ohun to mu ki fiimu naa yato ni ifarajin si otito ibile, ati iwakiri pataki isoro awujo re. A se opolopo akitiyan si inu iwadi ati sise afihan awon iha ariwa Naijiria pelu ibowo fun ati isedeede, eyi si gba opolopo odun. A safihan asa ati ise to dara ti won n fi oju bo mole ni awon fiimu kan.”

 

Chloe, to se igbeyawo pelu agberejade, Toka McBaror, fikun un pe oun fe ki fiimu naa la awon eniyan loju pe gbogbo awon ajinigbe ko ni oluso agbo eran.

 

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here