Èmi ò kì ń se àkọsílẹ̀ àwọn orin mi – Shallipopi
Mary Fágbohùn
Olorin to n dide bo Crown Uzama ti a mo si Shallipopi ti safihan pe oun kii ko awon orin oun sile.
Shallipopi, eni to de ipo okiki pelu orin takasufe igboro “Elon Musk,” so ona to n gba ko orin bii “didaraofe” ninu iforo-wani-lenu-wo kan pelu Do2tun lori eto ile ise asoromagbesi Cool FM.
O gba pe oun maa n daraofe si gbogbo orin, koda awon to wa ninu awo orin to n sise le lori EP, Planet Pluto.
Shallipopi fikun un pe awon orin naa ni won n gba sile laarin wakati meji.
O tesiwaju nipa sise alaye pe ipinnu re lati ma ko awon orin re sile.
O ni sise bee yoo je ko da bii aigbafe ati pe o duro lori pe o ye ki orin je ‘idaraya ati efe sise’.
‘”Ti mo ba ko o sile, yoo farajo sise ise lokunkundun ati pe yoo si le ju.