Ó ye̩ kí àwo̩n olórin ìhìnrere dé̩kun àti máa dápárá sórin bíi tàwo̩n olórin ayé — ZionGrace

 

 

Ó ye̩ kí àwo̩n olórin ìhìnrere dé̩kun àti máa dápárá sórin bíi tàwo̩n olórin ayé — ZionGrace

Mary Fágbohùn

Olorin ihinrere to sese n goke bo, Grace Owolabi, ti a mo si ZionGrace, ti ro awon olorin ihinrere akegbe re lati dekun ati maa dapara sorin bi tawon olorin aye.

O so fun Sunday Scoop pe, “Mimu asa didapara ni o ye ki won dipo pelu awon oro orin ti yoo mu iyi ba Kristi. Awa (olorin ihinrere) gbodo dekun ati maa se akose didapara aye ati lati maa jijo won. Pupo ninu awon apara yii ati ijo wonyii lo wa latodo esu. A ko le e gbe ounje fun Olorun pelu awon eroja ti ko mo. Ko ti e ni wo; ka ma to so pe yoo gba. Bibeli so pe awa ni ‘iyo ati imole aye’. Awon to wa ninu aye lo ye ko fi wa se awokose, kii se awa.”

Olorin naa wi pe oun le e ba olorin alailesin korin to ba je ife Olorun ni. O wi pe, “Bee ni mo le se; sugbon to ba je ife Olorun ni. Maa wo oju Olorun ki n to se iru akopo orin bee; bo ti e je olorin ihinrere pelu. Orin alailesin yato si orin aye. Ero ti a ni tele ni, imolara, oye ati igbagbo ti o safihan bi Olorun se ri; sugbon ti eleyii si n safihan erongba, imolara ati igbagbo ti aye.”

ZionGrace, eni to sese keko gboye Master ni Public Health, tun ro awon oluso aguntan lati ran awon olorin ihinrere won lowo.

Nigba to n soro lori awo orin re to pe akole re ni, Yahweh, o wi pe, “Bi ti awon orin mi tele, mo ri bi ise lati ko awon orin miiran ti o kun fun irusoke lati bukun orile-ede. Bo ti le je pe, mo ni orin ti o to ogorun-un sile, mo gbodo gbadura lati ni oye ohun ti Olorun ni lokan fun awon eniyan re, ati ohun ti yoo je akole awo naa. Bi ida ogorin awo orin naa ni mo sese ko nipase imisi Emi mimo. Leyin naa, mo bere si ni ko orin naa pelu awon elegbe mi.

“Orin mi je ara eto, to si ma n dojuko titobi Olorun m, imoore, asotele, iranse ireti ati ironupiwada ni pupo igba. Ara orin mi da lori imisi Emi mimo; sugbon awo orin yi je idapo takasufe ati alujo; bee gege ni afro ati awon orin ihinrere.

 

 

 

 

 

 

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here