Burna Boy, Tems àti Rema seré níbi NBA Halftime Show

Burna Boy, Tems àti Rema seré níbi NBA Halftime Show

Mary Fágbohùn

Olugbafe eye grammy, Damini Ogulu, ti a mo si Burna Boy ati Tems pelu Rema korin nibi NBA All-Star game halfshow ti 2023.

NBA All-Star game halfshow ti 2023 ni won se ni Salt Lake City, USA ni ojo Aiku.

Are Afrobeat naa side pelu Burna Boy, eni to ko orin re to gbori lodo gbogbo eniyan “It’s Plenty” ati “Anybody”. Leyin Burna ni Rema eni to mu ori awon eniyan wu pelu “Calm Down” ati “Holiday”.

Tems si kase eto naa nle pelu orin lara orin re “Crazy Tings, Free Mind” ati ipa re to ko ninu orin “Essence” pelu Wizkid ti “Wait For U” Feature si wa lare re.

Are naa tun mu ki Burna Boy ko orin to gbori lodo opo eniyan “Last Last”.

 

 

 

 

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here