Saudi Arabia gbo ewúròó s’ójú Argentina

Saudi Arabia gbo ewúròó s’ójú Argentina

Yinka Alabi
Ara o ki n tan nile alara nigba kankan ge̩ge̩ bi ipede Yoruba.
Nigba ti o̩po̩ eniyan gbo̩ pe orileede Lionel Messi ni Saudi Arabia maa ba fagagbaga ninu idije du ife e̩ye̩ Agbaye to n lo̩ lo̩wo̩ ni orileede Qatar. Awo̩n eniyan ni ape̩re̩ ni orileede Saudi fi maa ko bo̩o̩lu naa.
Orileede Argentina ti se ifigagbaga me̩rindinlogoji (36) ti wo̩n si bori gbogbo re̩.
iyale̩nu nla ni o je̩ nigba ti orileede Saudi bori idije naa pe̩lu ami ayo meji si e̩yo̩kan.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here