Qatar fìtàn bale̩ ní World cup
Yínká Àlàbí
Orileede Qatar ni o gbalejo ere bo̩o̩lu idije du ife e̩ye̩ ti agbaye o̩dun 2022 yii.
Fun igba ako̩ko̩ lati igba ti ere bo̩o̩lu naa ti be̩re̩ ni o̩jo̩ ke̩tala osu keje o̩dun 1930, olugbalejo ni o ko̩ko̩ maa n gba bo̩o̩lu lati side. Be̩e̩ ge̩le̩ naa ni o ri , amo̩ igba ako̩ko̩ niyi ti olugbalejo maa lule̩ nibi idije ife Agbaaye naa.
Orileede Qatar lule̩ pe̩lu ami ayo meji si odo lo̩wo̩ orileede Ecuador.