Spain gb’adé bọ́ọ̀lù àgbáyé

Orileede Spain lo jawe olubori ninu ere bọọlu agbaye to bẹrẹ pẹlu orileede mejidinlaadọta.
Mejidinlaadọta ku mẹrindinlogun, lẹhin naa lo ku mẹjọ,lati mẹjọ lo ti ku mẹrin.
Awọn orileede mẹrin lo ti ku meji. Ninu awọn meji ni orileede Spain ti gbena woju Argentina pẹlu ami ayo kan pere.
Orisiirisii ami ẹyẹ lo tun waye lọjọ kọkandinlogun osu keje ọdun yii.
Diẹ lara awọn to gba ami ẹyẹ naa ni –

*FIFA 🇺🇸 WORLD 🇨🇦 CUP 🇲🇽2026*

*FINAL*

*Spain 🇪🇸 1*
Argentina 🇦🇷 0

*ÀMÌ Ẹ̀YẸ*

🏅 Golden Boot: *Kylian Mbappe 🇫🇷*
🏅 Player of the Tournament: *Rodri 🇪🇸*
🏅 Young Player of the Tournament: *Pau Cubarsí 🇪🇸*
🏅 Golden Glove: *Unai Simón 🇪🇸*

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here