Ọba Ẹ́ṣàòkè wàjà
Láti Ìròyìn òwúrọ̀
Owamiran ti Esaoke, Oba Adeyemi Adediran, Atipa Owaji II ti wọ kaa ilẹ lẹyin aisan ranpẹ.
Isede ti wa ni gbogbo ilu lati le se etutu to yẹ ki eku ilu le ke bii eku, ki awọn ọmọ eniyan naa le maa fọhun bii eniyan.
Ilu Ẹṣaoke wa lara ilu ilẹ Ijẹsa to wa ni ipinlẹ Ọṣun.
Ki Eledua tẹ Oba si afẹfẹ ire.









