Ẹran Ràgó kan ènìyàn kan ni gbogbo òsìṣẹ́ Oṣòdì/Ìṣọlọ̀ gbà fún Kérésìmesì
Yínká Àlàbí
Honourable Kehinde Oloyede tii ṣe alaga ijọba ibilẹ Oṣodi Iṣọlọ ṣe bẹbẹ lasiko ọdun keresimesi yii.
Ẹran rago kọọkan fun osisẹ kọọkan pẹlu awọn nnkan miiran ni awọn osisẹ gbe lọle f’ọdun.
Awọn osisẹ yii fẹrẹ le maa sepe nibi ti adura wọn pọ to. Wọn ni iru rẹ ko sẹlẹ ri, eyi si mu ki wọn maa fẹmi imoore han ninu fidio isalẹ.









