Wasiu Ayinde gbé Dapọ Abiodun lọ ilé ẹjọ́ nítorí ipò Awujalẹ

Wasiu Ayinde gbé Dapọ Abiodun lọ ilé ẹjọ́ nítorí ipò Awujalẹ

Yínká Àlàbí

King Wasiu Ayinde Marshall 1 (KWAM 1) ti sọ ọ̀rọ̀ ipo Oba Awujale ti Ijebu di ọrọ ile ẹjọ.
K1 ni wọn o le maa f’ọbọ lọ oun lori ipo ti oun lẹtọọ si. O ni oun se eleyii nigba ti oun gbọ pe gomina ipinlẹ Ogun, Dapo Abiodun ti fẹ fi ọmọ oye jẹ laipẹ.
Ẹjọ naa da lori bi ile ọba ti oye kan naa, ẹbi Fusengbuwa se kọ lati yẹ iwe ti oun ko pe oun maa nifẹẹ si ipo Awujale.
Iwe ipe lẹjọ naa jade ni ọjọ kejidinlogun osu yii, igbẹjọ si maa waye ni ọjọ kejilelogun osu yii.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here