Lennart Karl fìtàn balẹ́ ní Champions League games
Yínká Àlàbí
Ọdún mẹ́ta léra-léra ni ọ̀dọ́mọdékùnrin agbábọ́ọ̀lù, Lennart Karl fi n gbá boolu wọle alatako ninu idije Champions League games.
Eyi ko tii sẹlẹ̀ rí láti ìgbà tí ìdíje náà ti bẹ̀rẹ̀.
O
Ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún péré ni Karl.










