N kò lè dáwó̩ è̩bùn fún àwo̩n afé̩nifé̩re mi dúró – Myspro
Mary Fágbohùn
Olorin to sese n dide bo, Myspro, ti so pe oun yoo maa fun awon afenifere oun ni nnkan to yato si eyi to wa ni ita loorekoore.
Nigba to n soro lori imisi orin re to sese gbe jade, Nonstop, ninu eyi ti Perruzi ati Jamopyper ti korin, ati itewogba ti o je gbadun, olorin naa wi pe, “Bi a se n soro yi, orin naa n se daadaa. Ohun ti o ya a soto ni ifijise, eyi to mu ki ogooro eniyan sapejuwe re bii ‘ikoja ala to dara’. Imarayagaga orin le e mu opolopo lo lati inu orin ife naa.
“Imisi fun orin naa waye latari itara lati fun awon afenifere ni nnkan to yato. Ajosepo naa lo ni melomelo pelu, nitori mo ti mo Jamopyper fun igba pipe. Ni igba ti akoko to ye si to, gbogbo wa kan se nnkan fun awon afenifere lati jo si.”
Nigba to n seranti eto iseda to nise ninu ajosepo pelu Peruzzi ati Jamopyper, o wi pe, “Mo le e korin pelu eyikeyi ohun, eyi ni nnkan ti a n reti lati odo olorin to dara. O nilo lati fun awon eniyan ni nnkan to dara ti o si yato. Ati pe, gbogbo wa fi orin naa jise.”