Israel DMW fèsì bí Anita Brown se so̩ pé Davido ń fi ìyà je̩ Chioma

Israel DMW fèsì bí Anita Brown se so̩ pé Davido ń fi ìyà je̩ Chioma

Mary Fágbohùn

Alakoso eekaderi Davido, Israel DMW, ti fesi si oro ti orebinrin Amerika to so pe oun loyun fun olorin naa, Anita Brown wi pe “o n na obinrin.”

Anita Brown fi esun kan Davido lori itan Instagram re pe o n na iyawo re, Chioma, eni to je orebinrin re ni igba naa, “lai saanu re” lori oro “eni to pe ni orebinrin miran.”

O tun fi esun kan Davido pe o n se Chioma riboribo, o tenumo o pe igbeyawo won ko layo.

O ko o wi pe, “O je nnkan ibanuje nitori pe o je eni to n na obinrin, loooto. O ye ki n ti mo ti pe pe opuro ni, eni to n se eniyan riboribo ni to si feran isakoso.

“Tu Chioma sile ninu ibasepo asilo! Asilo nipa ti enu ati asilo nipa ti opolo.”

Nigba ti yoo fesi lori ayelujara re, Israel DMW safihan iyalenu lori esun ti Anita fi kan Davido.

O so pe gbogbo ogbon ati fa eniyan wa sile yi yoo pada to Anita Brown.

O so pe, “Oga, na iyawo won bawo? Nigba wo, nitori Olorun? Ife re ko le e pe kun. Ma se iyonu.”

 

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here