Síse e̩lé̩yà Chioma, gbígba ife è̩ye̩ Grammy di èèwò̩ – Uche Maduagwu so̩ fún Davido

Síse e̩lé̩yà Chioma, gbígba ife è̩ye̩ Grammy di èèwò̩ – Uche Maduagwu so̩ fún Davido

Mary Fágbohùn

Alariyanjiyan osere tiata, Uche Maduagwu ti seleri pe olorin, Davido ko ni jawe olubori lati gba ife eye orin to niyi ju lagbaye, Grammy nitori pe o so iyawo re, Chioma di eni ti awon eniyan fi n rerin.

O so pe olorin naa fi iyawo re eni to si n kedun iku omokunrin re, Ifeanyi, se eleya ni gbangba, nipa fi fun obinrin meji miran loyun.

E ranti pe onirawo oju awe Onlyfan Amerika, Anita Brown ati awose French Ivana Bay pariwo sita laipe yi pe Davido fun awon mejeeji loyun.

Nigba ti yoo fesi lori Instagram re, Maduagwu so pe Davido ko le e duro lati sajoyo odun akoko ninu igbeyawo re pelu Chioma saaju ki o to bere si ni yan aale.

O wi pe, “Fun esin gbangba ti o n fi Chiom Chiom [Chioma] mi la koja yi, o o ni gboorun Grammy.

“E o ti sajoyo ajodun odun akoko ninu igbeyawo, won ti fi esun kan o pe o n pin oyun bi eni pin eran agbo ileya.”

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here