Ògbóǹtarìgì òsèré tíátà Iyabo Oko kú ní e̩ni o̩dún mó̩kànléló̩gó̩ta

Ògbóǹtarìgì òsèré tíátà Iyabo Oko kú ní e̩ni o̩dún mó̩kànléló̩gó̩ta

Mary Fágbohùn

Ilumooka osere tiata Yoruba, Sidikat Odunkanwi ti a mo si Iyabo Oko, ti je Olorun nipe.

Nigba ti o kede iku re ni ori Facebook ni Ojobo, okan lara awon omobinrin osere naa, Bisi Aisha so pe Iyabo Oko jade laye ni Ojoru.

O ko o wi pe: “Sun n re o iya mi.”

Nigba ti oun pelu fi aworan oloogbe naa lede ni ori Facebook re, osere tiata Iyabo Ojo ko o pe: “Ile ise fiimu Naijiria n kedun. Ogbontarigi osere tiata Iyabo OKO ti jade laye.”

Eni odun mokanlelogota naa saaju ipapoda re ni o ti n ja fitafita pelu ailera eyi to se okunfa idaduro nibi ise ere sise.

 

 

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here