Òsèré tíátà, Péjú bínú lórí ìbo̩n tí wó̩n yìn níbi tí wó̩n ti ń ya fíìmù

Òsèré tíátà, Péjú bínú lórí ìbo̩n tí wó̩n yìn níbi tí wó̩n ti ń ya fíìmù

Mary Fágbohùn

Fonran osere tiata Yoruba, Peju Ogunmola n lo kaakiri nibi ti osere naa ti n ni irunu si akegbe re lori ibon ti won yin nibi ti won ti n ya fiimu.

Osere eni odun merin-din-ni-ogota naa, eni ti ko mo pe won ro ibon naa, fi aidunnu re han si oludari ere ati agberejde, o wi pe won ko so fun oun.

Peju tun salaye pe oun ti so fun oludari naa lati yoo oun kuro ninu iran ti won ibon ba wa tabi ti won yoo ti yinbon.

Ninu fonran naa, o wi pe, “Mi o feran re, o mo pe mi o feran re, o o so fun mi.

“O o so fun mi, okan so fun mi pe won yoo lu mi lasan ni, kii se ki won yin mi nibon.”

Gege bi osere alawada, oludari ati agberejade,Peju ti fun ara re ni maa ki to ga ninu ile-ise fiimu.

Lara awon fiimu re ti awon eniyan mo ni

Maradona (2003), Mafi wonmi (2008), Toromade (2009), ati Apaadi.

Ogbontarigi osere naa se igbeyawo pelu osere alawada ati agberejade, Sunday Omobolanle ti a mo kaakiri si Papiluwe. Olorun si bukun asopo won pelu omokunrin kan, Sola.

 

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here