Bí mo se gbèrò láti sé̩gun ilé-isé̩ orin — D’ruze

Bí mo se gbèrò láti sé̩gun ilé-isé̩ orin — D’ruze

Mary Fágbohùn

Olorin to sese n dagba bo, akorin sile ati awose ewa, OgheneRume Gbinijie, ti a mo si D’ruze, ti so pe oun n gbero lati bo ile-ise orin mole pelu orin oun to je ara-oto. Ninu oro kan to fi ranse si Saturday Beats, o wipe, “Orin bere funmi lati igba kekere, ti ina ife ti mo ni si orin si njo si i.

Mo bere nipa sise ‘atunko’ awon orin ti gbogbo eniyan mo. Ni titele imoran ti awon ore mi, ebi ati awon aferenifere gba mi, mo se ipinnu lati wo inu ile-ise orin. Erongba mi ni lati segun ile-ise orin pelu orin mi to je ara oto afropop ati afrobeat ti duru si n gbe lese.”

Nigba to n soro nipa orin re tuntun kansoso ti o pe akole re ni, ‘Superman’, olorin naa wi pe, “O je mimu, ti mo ko pelu duru ti yoo mu ki awon olugbo dide lori ese won. O tun safihan awon eroja tuntun to je ko yato si awon orin duru miiran. Ilepa mi gegebi olorin ni lati maa mu inu awon ololufe mi dun nipa fifun won ni ohun to dara ti won si mo nipa re. O dami loju pe eyi ko le je iyato. Gbogbo awon ti won ti gbo orin naa feran re, o dami loju pe yoo je orin ti gbogbo eniyan gba tire lagbaye.”

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here