Ìdùnnú subú layọ nílé gomina Ademola Adeleke

Idunnu subu layọ nile gomina Ademola Adeleke latari bi o se jawe olubori nibi ibo to waye lanaa, ọjọ keedogun, osu keji yii.
Idibo lagbara pupọ de bi wi pe aye gbọ, ọrun gan an si mọ.
Ibo iye eniyan to le ni ẹẹdẹgbẹta ni o fi na (511,067) akẹgbe rẹ Bola Oyebamji ti ẹgbẹ oselu APC to ni ibo iye eniyan to le daadaa ni irinwo (444,816).
Ẹni to se ipo kẹta ni Najeem Salaan lati inu ẹgbẹ oselu ADC pelu ibo iye eniyan to le ni ẹgbẹrun mẹtadinlogun (17,180).
Eyi waye gẹgẹ bi ikede Ọjọgbọn Joshua Olalekan Ogunwole to jẹ oludari ibo naa ni ipinlẹ Ọṣun.
Bi eniyan meji ba kuku n tayo, ti ko ba ti jẹ ọmi, enikan lo maa jawe olubori. Ẹgbẹ oselu Accord lo gbegba oroke nibi ibo naa.
Ẹ wo fidio naa.
https://www.facebook.com/share/v/1DrrTXjUbZ/

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here