ÀṢÀ ÀTI ÌṢE
Mike Adenuga @ 69: Oriki awon Ijebu
Ijebu omo alare, Omo Alare, Omo epe o ja Omo arojo joye, Omo alagemo ogun woyowoyo, Omo aladiye ogogomoga, Omo adiye balokun omilili, Ara orokun, ara o radiye, Omo ohun seni oyoyonyo, Oyoyo mayomo ohun seni olepani, Omo dudu ile komobe se njosi, Pupa tomo be se okuku sinle, Omo…
Read More »Òwe – Bí obìnrin bá ti pé̩ nílè o̩ko̩, àjé̩ ló ń dà.
Òwe – Bí obìnrin bá ti pé̩ nílè o̩ko̩, àjé̩ ló ń dà. E̩ wo fídío òwe ìsàle̩ yí, ki e̩ ní ìmò̩ kún ìmò̩ òwe yìn.
Read More »Òwe – Wèrè dùn ún wò, kò se é bí ló̩mo̩.
Òwe – Wèrè dùn ún wò, kò se é bí ló̩mo̩. E̩ wo fídíò ìsàlè̩ yí, kí e̩ lè ní ìmò̩ kún ìmò̩ òwe yín
Read More »OTOLORIN YORUBA: Itumo owe ‘Omo go, e ni o ma ku, pelu FIDIO
Okan lara awon owe Yoruba pataki ni ‘Omo go, e ni ko ma ku, kin lo tun n pa omo to ju ago lo?’. Kin ni itumo re? Asiko wo ni a maa n lo o? E wo hulehule re niu fidio kekere yii, lati owo Alagba Mudasiru Alabi, ti…
Read More »Ìtọpinpin àwọn oníròyìn ló jẹ́ kí wọ́n rí Profeṣsor Peller pa – Iyawo opidan naa
Alhaja Silifa Abiola Peller, eni to je iyawo Oloogbe Abiola Peller, ti se alaye bi awon aalagbapa (hired killers) se ri bale oun pa. Won ni ‘E mu u, e ki I, eranko bee ko ni oore.’ Opidan ti gbogbo aye mo si Professor Peller naa ki se eni kan…
Read More »Awon omo Alade yari: Yoruba fe gba’ra re lowo ajeji Fulani to n tele basubasu
. Akeredolu yari kanle . Olubadan ni ki Seriki Sasa fi owo sibi owo o gbe . Gani Adams n yona lenu lori laasigbo Wakili . Sunday Igboho si gegun kale Igbaniloju naa ti n lo, ojo pe die, sugbon bayii, o jo pe ile Yoruba ti setan ati gba…
Read More »Ó d’ọwọ́ àgbà, ó d’ọwọ́ èwe pẹ̀lú*
*Ó d’ọwọ́ àgbà, ó d’ọwọ́ èwe pẹ̀lú* *Àṣà àti ìṣe* Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹ̀yin àgbà bọ̀ ,ẹ móhùn bọnu pé ,báyé bá sèèsì tojú àgbà bàjẹ́, àìmọ̀wáhù wọn ni. Hun hùn hún ! Ayé ò nán-án ní àṣà ńlẹ̀ yí mọ́, ohun olóhun ni wọ́n ń toṣọ mọ́ láa níbi gbogbo…
Read More »Ìbà Elédùà
Ìbà Elédùà Láti o̩wó̩ È̩dáò̩tò̩ Agbeniyi *Ìbà Elédùà* Mo wo òréré ayé títí N ò rí ohun tó ṣe folú wé kìkìdá ọlá, kìkìdá iyì òun ẹ̀yẹ Ẹni mímọ́, ẹni ọlà tó dá ohun tó dá gbogbo wa Ẹni mímọ́ adákẹ́dájọ́ A wọ́ pooro ikú yè Pàkùlà kan gbòòrò tí…
Read More »Lai Mohammed pe Yorùbá níjà
Iforo-wa-ni-lenu wo laarin Minisita eto iroyin ati asa, Alhaji Lai Mohammed pelu Iroyin Owuro. Minisita ni ki a ma se gbagbe isese wa, Baba yii ni ki a fi gbogbo olaju gbe isese ati asa wa laruge. Iroyin Owuro – Ki a maa baa maa fi gbogbo igba beere nipa…
Read More »Àgùnbánirọ̀ tí ń sin ilẹ̀ bàbá rẹ̀ ní Ekiti tí s’aláìsí.
Agunbaniro, Oghomwen Omoruyi Honour, ti n sin ile baba re ni Ekiti ti d’oloogbe. Iroyin ni, Honour s’alaisi ni ana June 24 leyin ti o ni ori n fo oun. Honours setan ni eka Mass Communication lati ile iwe giga Auchi poly, won gbe lo si ile iwosan leyin ti…
Read More »