Lionel Messi fẹ̀hìntì níbi eré bọ́ọ̀lù gbígbá ní ẹni ọdún mọ́kàndínlógójì

Lionel Messi fẹ̀hìntì níbi eré bọ́ọ̀lù gbígbá ní ẹni ọdún mọ́kàndínlógójì

Ko si ohun to ni ibẹrẹ ti kii ni opin. Atamatase to n gba bọọlu bii pe oun la da bọọlu gbigba silẹ, ti ko bata bọọlu gbigba fun orileede Argentina rọ sibi kan.
Bọọlu ọlọrẹẹ-sọrẹẹ laarin Argentina pẹlu Benin ni Buenos Aires ni wón fi se ayẹyẹ asekagba naa. Messi gba boolu ikẹrindinlaadoje (126th goal) wọle nibi ayẹyẹ naa pẹlu ẹsẹ alaafia to mọọ lo ju.
Asọ to ni nọmba kẹwaa naa wa pọ lori papa isere l’ọjọ naa lati fi yẹẹ si. Idije ọdun yii lo fi jẹ idije ọdun kọkanlelogun to ti n soju orileede Argentina.
Lionel Messi fi bọọlu gbigba karakara silẹ bayii ni ẹni ọdun mọkandinlogogi (39 years old).

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here