Àwọn ọ̀dọ́ Benue gbégi dínà fún Peter Obi

Àwọn ọ̀dọ́ Benue gbégi dínà fún Peter Obi

Awọn ọdọ ipinlẹ Benue ni wọn faake kọri pe oludije du ipo Aare labe ẹgbẹ oselu National Democratic Congress (NDC), Alagba Peter Obi ko ni wọ ilu wọn.
Gbogbo akitiyan awọn ọlọpaa lati jẹ ki Peter Obi wọle lo ja si pabo. Orin ọtẹ ni wọn kọkọ fi daa pada lati ẹnu iloro papakọi ofurufu ipinlẹ Benue. Eyi da sun-kẹẹrẹ, fa-kẹẹrẹ silẹ ni agbegbe patakọ ofurufu naa.
Ijọba ipinlẹ Benue ni akoko ti Peter Obi wa jẹ akoko ti awọn ọdọ ipinlẹ naa n se ipade. Ijọba ipinlẹ ni o yẹ ki oludije du ipo Aarẹ naa kọ iwe si ijọba , ki aabo to daju to si peye lati odo ijoba le wa .Wọn ni oludije naa kii se eeyan lasan to kan le rin bi o ti wuu.
Ikoro oju ni oludije naa fi pada lati papako ofurufu naa.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here