Obasanjo bá Ọọni du ìjókòó
Aarẹ orileede yii tẹlẹ, Oloye Olusegun Obasanjo ni o lọ si ibi ayẹyẹ ọjọọbi Ọba Ọta, Ọba Adeyemi Abdulkabir.
Ọba pe aadọta loke eepẹ lo ba fi idunnu rẹ han nipa ayẹyẹ ni ilu naa.
Wasiu Ayinde K1 ni wọn pe si ibi ayẹyẹ naa gẹgẹ bi elere. K1 ti awọn kan ni ki sabaa pọn eniyan le lo kọkọ na gbalaja si iwaju Ẹbọra Owu ni eyi to mu ki Obasanjo gba gbohun-gbohun lati ba awọn eniyan sọrọ.
Igba ti Obasanjo maa jokoo lo ba ni aga to tobi ju ni oun maa jokoo le nitori pe Aarẹ orileede tẹlẹ ri ju eyikeyi Ọba lọ.
Bi wọn se yọ orukọ Ọọni ti Ile-Ifẹ, Oba Adeyeye Ogunwusi kuro nibẹ niyi ti wọn si fi ti Aarẹ ana sibẹ.
Eyi fa alaye pelu apeere ati eebu leekookan lori ayelujara. Awon Kan to si eyin Obasanjo pe ooto ni bee ni awon Kan ni o fi ori ade gbole pelu ohun to se.









