PSG máa na Arsenal pa ní ìpele àsekágbá UCL – Olólùfẹ́ PSG

PSG máa na Arsenal pa ní ìpele àsekágbá UCL – Olólùfẹ́ PSG

Yínkà Àlàbí

Ọgbọnjọ osu yii ni ikọ Paris Saint-Germain (PSG) maa wako pẹlu Arsenal ni ipele asekagba.
UEFA Champions League (UCL) maa wa sopin ni ipari osu yii. PSG ni ife ẹyẹ naa wa lọwọ rẹ. Eyi lo mu ki awọn olutẹle ikọ naa maa fọwọ gbaya pe awọn maa se ibawi fun Ikọ Arsenal.
Awọn olutẹle Arsenal naa ni ipade di ọgbọnjọ osu yii ki awọn to mọ ẹni tó tó gbangba sun l’ọyẹ.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here