Ẹ gba mí o – 2face Idibia

Ẹ gba mí o – 2face Idibia

Yinka Alabi

Awuyewuye to wa laarin Natasha ati 2Baba lo mu ki gbaju-gbaja olorin n ni Teniola Apata, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Teni Makanaki, ti fèsì sí ìpè ìrànlọ́wọ́ tí Innocent ‘2Baba’ Idibia ké lórí ero ayelujara nipa Aṣòfin Edo, Natasha Osawaru. Adugbo ara eni ye ti wa laarin won to bii ojo meloo Kan.
O wa dabi eni pe 2baba ko le paa Moran lo je ki o ke gbajare pe ki araye o gba oun lowo Ogun Natasha.
Ipinni leni yii ti waye nigba Kan ni ilu London ti awon olopaa ibe ba won da sii ki o to tun wa di pe 2baba ke sita.
ti ń lọ.
Ori ero ayelujara Instagram ni 2baba ti pariwo “e gba mi” sita.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here