Ambassador Road Safety náà fojú hàn “e̩ wo fídíò re̩ nísàlè̩”
Yínká Àlàbí
O̩ro̩ bii ere ori itage o le tete kuro lorileede yii. ko tii to̩jo̩ be̩e̩ ni ko t’osu ti awuyewuye waye ni papako̩ ofurufu wa ti awo̩n ti aje ibaje̩ naa se̩ si lo̩wo̩ di asoju o̩ko̩ ofurufu.
Asoju o̩ko̩ ori ile̩ naa foju han ninu ileese̩ awo̩n e̩so̩ oju ona ni eleyii ti se̩le̩.
Gbogbo aye si n reti idajo̩.