ÀṢÀ ÀTI ÌṢE
Ó d’ọwọ́ àgbà, ó d’ọwọ́ èwe pẹ̀lú*
*Ó d’ọwọ́ àgbà, ó d’ọwọ́ èwe pẹ̀lú* *Àṣà àti ìṣe* Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹ̀yin àgbà bọ̀ ,ẹ móhùn bọnu pé ,báyé bá sèèsì tojú àgbà bàjẹ́, àìmọ̀wáhù wọn ni. Hun hùn hún ! Ayé ò nán-án ní àṣà ńlẹ̀ yí mọ́, ohun olóhun ni wọ́n ń toṣọ mọ́ láa níbi gbogbo…
Read More »Ìbà Elédùà
Ìbà Elédùà Láti o̩wó̩ È̩dáò̩tò̩ Agbeniyi *Ìbà Elédùà* Mo wo òréré ayé títí N ò rí ohun tó ṣe folú wé kìkìdá ọlá, kìkìdá iyì òun ẹ̀yẹ Ẹni mímọ́, ẹni ọlà tó dá ohun tó dá gbogbo wa Ẹni mímọ́ adákẹ́dájọ́ A wọ́ pooro ikú yè Pàkùlà kan gbòòrò tí…
Read More »Lai Mohammed pe Yorùbá níjà
Iforo-wa-ni-lenu wo laarin Minisita eto iroyin ati asa, Alhaji Lai Mohammed pelu Iroyin Owuro. Minisita ni ki a ma se gbagbe isese wa, Baba yii ni ki a fi gbogbo olaju gbe isese ati asa wa laruge. Iroyin Owuro – Ki a maa baa maa fi gbogbo igba beere nipa…
Read More »Àgùnbánirọ̀ tí ń sin ilẹ̀ bàbá rẹ̀ ní Ekiti tí s’aláìsí.
Agunbaniro, Oghomwen Omoruyi Honour, ti n sin ile baba re ni Ekiti ti d’oloogbe. Iroyin ni, Honour s’alaisi ni ana June 24 leyin ti o ni ori n fo oun. Honours setan ni eka Mass Communication lati ile iwe giga Auchi poly, won gbe lo si ile iwosan leyin ti…
Read More »ìdíje FIFA Women World Cup: Naijiria na Korea 2 – 0.
Awon agbaboolu obinrin ti orile-ede Naijiria ti ni anfaani lati koja si ipele to n bo ninu FIFA Women World Cup ti n lo lowo leyin ti won na South Korea ni 2 – 0, Agbaboolu ipinle South Korea, Kim Doyeon lo fun wa ni goolu kan, ti Asisat Oshoala…
Read More »Arábìnrin tó rẹwà yìí ń fi ìlà ojú rè hàn.
Arabinri yii n fi igberaga ati owo lati fi ila oju re han. O ni oun ni obinrin to dara ju to ni ila to rewa ju, oun o si tiju lati fi han.
Read More »Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Babajide Sanwo-Olu ti ṣe ìbúra fún àwọn akọ̀wé lailai tuntun tí wón ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn
Gomina ipinle Eko, Babajide Sanwo-Olu ti se ibura fun akowe lailai (Permanent Secetary) tuntun mẹ́fà tí won sese yan. Gbolohun ti olori ise(head of service) ipinle eko, Hakeem Muri-Okunola, ni igbese naa ni lati maa tele ofin ipinle lati maa yan awon eeyan tuntun, o si ise won ti bere…
Read More »Àkókò Bukola Saraki gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ Sẹ́nètì ti dópin.
Aare National Assembly Kejo, Bukola Sakari ti so oro keyin gege bi aaare seneti, ninu apejopo igbimo lonii. Saraki ni “lonii, a se igbimo apero keyin. O je isegun pe avri igbeyin irinajo naa. O je majemu si nnkan daadaa ti àwọn eeyan le se ti won ba pawopo. O…
Read More »Àwòrán Aláàfin Ọ̀yọ́ àti àwọn ìyàwó rẹ̀.
Oba Lamidi Adeyemi, Alaafin Oyo pelu awon iyawo re, lo gba adura Eid ni Agunpopo Muslim praying ground ni Oyo.
Read More »Ààrẹ Buhari lọ gba àdúrà Eid El Filtri ní Mabilla Barracks.
Ni aaro eni, aare Buhari lo gba adura Eid El Filtri ni Mabilla Barracks Praying Ground.
Read More »