WAEC 2025: Boluwatife̩ fako̩ yo̩

WAEC 2025: Boluwatife̩ fako̩ yo̩

Yínká Àlàbí

Bo se wu Oluwa lo n se o̩la re̩. O̩ruko̩ o̩do̩mo̩debinrin yii roo. Esi idanwo to gbe lo̩wo̩, o̩mo̩ ile iwe aladaani to maa gbe iru re̩ jade lo̩dun yii mo̩ oju ara re̩.
Ileewe Senior Government College, Agege ni Boluwatife̩ Akintoye ti pari e̩ko̩ re̩ to si gbe iru esi idanwo to dara bayii jade.
O̩do̩mode yii ye̩ ko gba e̩bun ijo̩ba koda o le je̩ ti ijo̩ba ibile̩ tabi ti ipinle̩ tabi mejeeji ti ko ba ri ti ijo̩ba apapo̩ gba.