Home Orisirisi Ounje ati obe to wa ni ile Yoruba

Orisirisi Ounje ati obe to wa ni ile Yoruba

Lolade Ogunbowale

Nje e mo pe Yoruba ni to orisii ounje to fee to aadorin? Eyi ko ni sai ya opo eniyan lenu.
Ni bayii, IROYIN OWURO fe daruko irufe awon ounje, paapaa obe aladun naa, gege bi ajo Centre for Black Culture and International Understanding, eyi to wa ni Osogbo, ni Ipinle Osun, se gbe e kale.
Awon ounje naa niyi:
1. Ekuru alaro
2. Ekuru alaro pelu ata dindin
3. Ekuru funfun
4. Iro
5. Monki
6. Dodo Ikire
7. Dele
8. Abari onisu
9. Egbo ati ewa
10. Adalu
11. Asaro
12. Mosa
13. Feregede
14. Akara osu
15. Isu ewe
16. Iyan gbeere
17. Eko
18. Serekesin
19. Akara ikoko
20. Akara orudu
21. Otika tabi burukutu
22. Emu
23. Iyan isu pelu anamo
24. Eko yangan
25. Eko baba
26. Ori (Shea butter)
27. Sapon
28. Agidi
29. Obe eku gbigbe
30. Luuru
31. Iresi Fulani
32. Eko eda
33. Obe ikoto
34. Koto akoje
35. Obe toketile
36. Obe eku tutu tabi Morogbo
37. Ilasa
38. Tapioca
39. Wanke
40. Abari tabi Sapala
41. Ebiripo
42. Egusi Ijebu
43. Ikokore
44. Ojojo koko
45. Ojojo ewura
46. Iresi ofada pelu obe ata dudu
47. Obe gbonpete
48. Opoporu
49. Ewa aganin
50. Kango
51. Obe gbanunu
52. Iyan egidi
53. Egusi funfun
54. Obe ila funfun
55. Kati
56. Akara isikiri
57. Akara epa
58. Elekute
59. Obe ikowu tabi papu
60. Ataokuta
61. Ufo
62. Ipekere oloka
63. Obe Eremo
64. Pupuru
65. Eepa
66. Kakore
67. Iyan Lambo
68. Obe ikan.