Super Eagles Naijiria fàgbà han akẹgbẹ́ wọn láti Tanzania pẹ̀lú àmì ayò méjì sí ẹyọkan
Yínká Àlàbí
Ikọ agbabọọlu Super Eagles gbo ewuro si oju akẹgbẹ wọn lati ilu Tanzania pẹlu ami ayo meji si ẹyọkan.
Orileede Morocco ni papa isere Fez ni idije bọọlu naa ti waye.
AFCON 2025 ni orukọ idije adulawọ naa.









