Sowore máa fojú ba ilé ẹjọ́ ní ọjọ́ ‘Bọ

Sowore máa fojú ba ilé ẹjọ́ ní ọjọ́ ‘Bọ

Yínká Àlàbí

Alasẹ ati oludari Sahara Reporters, Omoyele Sowore maa foju ba ile ẹjọ ni ọjọ ‘Bọ tii se ọjọ kẹrinla, osu kẹjọ ọdun yii fun awọn ẹsun mẹta ti ajọ ọlọpaa fi kan an.
Agọ ọlọpaa ni o ti n salaye yii nigba ti won fi ọwọ sinkun ofin tii mọle fun ọjọ mẹta ni ilu Abuja. Sowore ni awọn ẹsun mẹtẹẹta naa ni “wọn ni mo n ti awọn afẹyinti ọlọpaa lẹyin lati da ilu ru, wọn ni mo n lọwọ ninu jibiti ayelujara, wọn tun ni awọn lepa mi de bi ibi ti mo ti ni nnkan se pẹlu awọn afẹmisofo.
Sowore ni ti ika ba rojọ, ika ko ni yoo da a, ipade di ile ẹjọ.