Small Doctore sè’kìlò fáwọn tó ń wọ ọkọ̀ kórópe
Mary Fágbohùn
Olorin Small Doctor ti se’kilo fun awon araalu nipa ewu to wa ninu wiwo oko elero ti a n pe ni “Korope”, ti won ni agbero.
Lori X o ni ida aadorun un ninu ogorun un (90%) ninu awon oko naa ni won ni erongba miran eyi to le mu iwa afunrasi lowo.
Lati ri daju pe aabo wa, Small Doctor gba awon ti awon arinrinajo lati sora ati pe ki won yago fun wiwo iru oko bee.
O ko o pe, “Ti e ba fe wo oko akero kekere (Korope) to ni agbero, e ma se wo o. E MASE WO O. E MA WO. Ida aadorun un ninu won lo ni ohun miiran lokan lati se. E sora.”