Shoprite di títì pa nítorí owó orí
Yínká Àlàbí
Ileesẹ to n se akoso owo ori LIRS ti gbe agadagodo si ile itaja gbaju-gbaja Shoprite to wa ni Ikeja.
Ileese yiin wọn ko tẹle ofin owo ori. Wọn si ti jẹ owo to pọ ti wọn ko si kọ ibi ara si sisan rẹ rara.
Ileesẹ LIRS ni agadagodo ti awọn gbe si ẹnu ọna wọn ko gbọdọ jẹ sisi lai se pe awọn ti awọn tii ni awọn sii, ti enikẹni ba dan sisi rẹ wo yoo fi ewon jura.
LIRS ni ti ko ba da wọn loju ki wọn lọ si iwe ofin ilẹ wa ni abala owo ori to wa ni ori kẹrinlelaadọrun-un ti ọdun 2011 (94 of the Personal Income Tax Act, 2011).









