Òun lo̩kàn mí yàn ló jé̩ kí n fi s’adé orí – Temi O̩te̩do̩la
Mary Fágbohùn
Osere tiata Temi Otedola, omobinrin olowo tabua, Femi Otedola, ti soro nipa ohun to je ko fe olorin, Mr Eazi.
Ninu iforowero laipe pelu BBC, Temi salaye pe oun segbeyawo pelu olorin naa nitori pe o je ore timotimo oun pelu awon idi miran.
O ni bawo ni igbe aye oun i ba se ri laisi Mr Eazi nibe nitori oun ko ro pe elomiran le e dabi re ninu aye oun.
Oluforo-wani-lenu-wo beere pe: “Ki lohun to mu ko ‘gba’ fun Mr Eazi?”
Temi fesi: “Opolopo nnkan ni. Bawo ni mi se fe fowo mukan ninu re? Ani, saaju ohun gbogbo, ore timotimo mi ni. Eeyan mi ni. Mo si lero pe nigba ti o ba pade eeyan, waa mo.
“O je eeyan ti inu mi maa n dun lati lo gbogbo ojo pelu; ka jo ko igbe aye wa papo, ki a si rin ninu rukerudo bi a ti n sayojo ti a si n yanju isoro papo. Eeyan mi ni. Nitori naa, inu wa n dun fun ohun to n bo wa.”
Lori ohun to je ko yan lati je oruko oko re leyin igbeyawo, Temi wi pe, “Mo ti si ayaleko, o je ohun to kan leti je oruko oko mi. Sugbon mo laayo ni. Mo si bowo fun agbara obinrin lati yan ohun to fe.”
Irawo fiimu naa fikun un pe mimu ibasepo re kuro loju gbogbo aye je ki nnkan rorun fun un .
E ranti pe Temi ati Mr Eazi se igbeyawo ni ise die seyin seyin ni Iceland. Gbajumo olorin Amerika, John Legend korin nibi igbeyawo won.