Ọpẹ́ o! Dangote já owó epo petiró wálẹ̀

Ọpẹ́ o! Dangote já owó epo petiró wálẹ̀

Ìròyìn òwúrọ̀

Ileesẹ epo Dangote ti tun ja owo epo walẹ lati N828 si N699. Iye owo yii jẹ iye ti awọn to n gbe epo lọdọ rẹ maa gbe.
Eyi jẹ ida to le meedogun ninu ọgọrun owo epo ọja agbaaye to ja walẹ. Ọjọ kọkanla osu kejila yii naa lo yẹ ki awọn ara ilu ti maa jẹ anfaani ẹdinwo naa.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here