Obìnrin gb’àjo̩ba eré ìdárayá,
Oluebube àti Rosemary gbapò kín-ín-ní àti èkejì níbi eré sísá ní Algeria
Yínká Àlàbí
Awo̩n obinrin gb’ajo̩ba ere idaraya patapata ni orileede yii.
O̩s̩e̩ to ko̩ja ni awo̩n obinrin gb’efe e̩ye̩ WAFCON wole, o̩jo̩ isinmi yii ni awo̩n obinrin D’Tigress naa tun bori orileede Mali nibi ife e̩ye̩ alafowo-ju-sawo̩n, lo̩wo̩ lo̩wo̩ bayii ni Oluebube Ezechukwu ti sare ju gbogbo awo̩n ake̩gbe̩ re̩ nibi idije ere idaraya ti awo̩n ake̩ko̩o̩ Se̩ko̩ndiri to n lo̩ niluu Algeria. Rosemary Nwankwo ni o se ipo keji ni eyi to tumo̩ si pe awo̩n obinrin ko gba rara mo̩ lasiko Tinubu yii.
Idije ere idaraya naa maa pari ni o̩jo̩ tuside, o̩jo̩ karun un osu ke̩jo̩ yii.