O̩pé̩lo̩pé̩ òfin FIFA lórí bó̩ò̩lù aláfe̩sè̩gbá “e̩ wo fídíò bó̩ò̩lù ayé àtijó̩”
Yínká Àlàbí
Okiki bo̩o̩lu alafe̩se̩gba ko ba ma kan to bayii to ba je̩ pe bi wo̩n se n gba a ni aye atijo̩ naa la si n gba a lode oni.
Laye igba kan, ti agbabo̩o̩lu ba pofo bo̩o̩lu, ko gbo̩do̩ pofo e̩se̩ ni asa igba naa.
E̩ni to ba wo fidio yii maa beere orisiirisii ibeere bii – kin lo le to be̩e̩? Se ogun laye ni? Nitori kin ni? Ere idaraya leyi ni abi ere ati so̩ ni di alaabo̩ ara?
O̩pe̩lo̩pe̩ ajo̩ alakoso ere bo̩o̩lu FIFA (Fédération Internationale de Football Association) to be̩re̩ ni o̩dun 1904 pe̩lu awo̩n ofin ti ko faaye gba ika sise lori papa.
E̩ woo funra yin…