O̩pé̩ o! Aké̩kò̩ó̩kùnrin Fásítì Babcock di rírí

O̩pé̩ o! Aké̩kò̩ó̩kùnrin Fásítì Babcock di rírí

Yínká Àlàbí

Yoruba bo̩, wo̩n ni “o̩mo̩ bni ku san ju o̩mo̩ e̩ni nu lo̩” bi o tile̩ je pe ko sieyi to dara nibe̩.
Lati bi o̩jo̩ meloo kan ni abileko̩ Fijabi Oyindamo̩la figbe ta nipa o̩mo̩ re̩ todi awati ni ile iwe giga alafaani Babcock to wa ni ilu Ilisan-Re̩mo̩ ni ipinle̩ Ogun.
O̩ladipupo̩ Siwajuo̩la ni oruko̩ o̩do̩mo̩dekunrin naa. Bi ise̩le̩ yii sw se̩le̩ ni awo̩n o̩re̩, e̩bi ati ojulumo̩ ti be̩ sita lati se awari ake̩ko̩o̩ naa.
Isoro yii po̩ fun ile-iwe naa de bi wi pe asilewo̩ ti fe̩re̩ ba wo̩n. Idunnu subu layo̩ fun wo̩n nigba ti o̩mo̩ naa di riri.
Ohun to se̩le̩ si ake̩ko̩o̩ naa, bo se poora ati e̩ni to ko̩ko̩ rii ko ti te̩ wa lo̩wo̩ lasiko ti a n ko iroyin yii jo̩.
Eyi to kaakiri gbogno ori ayelujara ni pe O̩ladipupo̩ ti dele, obi je̩ri sii be̩e̩ naa si ni ile-iwe Fasiti Babcock naa ni ooto̩ ni.