Òǹtajà àti Òǹrajà Báńgà ló máa fojú winá òfin – Àjọ Ọlọ́pàá

Òǹtajà àti Òǹrajà Báńgà ló máa fojú winá òfin – Àjọ Ọlọ́pàá

Ìròyìn òwúrọ̀

Bi ijọba apapọ ṣe n fọnrere “ẹ ma ra Banga, ẹ ma yin banga” ni awọn ọlọpaa ipinlẹ naa n lọgun, koda ti ijọba ibilẹ kan tun niyi.
“Ọga ọlọpaa yii ni ti ọwọ ba tẹ ẹni to yin banga yoo mu awọn de ibi to ti raa”.
Yoruba bọ “wọn ni ẹnu onikan la ti n gbọ pọnhun”. Ẹ gbọọ lẹnu ọga ọlọpaa naa –

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here