Mo sì wà nínú ẹgbẹ́ PDP – Wike

Mo sì wà nínú ẹgbẹ́ PDP – Wike

Yínká Àlàbí

Mínísítà fún olú ìlú wa ní Abuja, Nyesom Wike lo n salaye yii fun awọn oniroyin nibi akanse isẹ́ kan to lọ ni ilu Abuja.
Wike ni awọn mẹ́rìndínlógún to fi ẹgbẹ́ oselu PDP silẹ̀ lọ si APC lẹ́tọ̀ọ́ lati se ohun to ba wu wọ́n lábẹ́ ofin ilẹ̀ wa.
“O ni awọn asoju yii o ki n se ọmọdé bí o tilẹ̀ jẹ́ pe wọn ko fi to mi leti ki wọn to lọ darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ APC. Ko si ohun to lodi sofin ninu ohun ti wọn se”.
“Mo si maa sisẹ́ pọ̀ pẹ̀lú awọn mọ́kanla to ku si ile igbimọ asofin ipinlẹ Rivers nitori pe emi si wa ninu ẹgbẹ́ PDP”.
Wike ni awọn ni lati sisẹ́ lórí ẹgbẹ́ náà kí ó ma baà parun.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here