Mo nífè̩é̩ Kanye West’ – Tems gba
Olorin Temilade Openiyi, ti a mo si Tems, ti safihan ife ti o ni si alawuyewuye orin kiakia Amerika, Kanye West.
Nigba to n soro lori eto ‘Shopping The Sneakers’ laipe yi, olorin ‘Mr Rebel’ naa so pe oun nifee Kanye West, o ni oun maa n ba soro leekookan.
Tems tun soro lori ibasepo re pelu irawo olorin R&B Amerika, Brent Faiyaz.
“Brent Faiyaz je ore mi daradara. Mo ti moo lati 2021. O je eniyan gidi. O maa n satileyin fun ni. Mo ni awon olorin ti mo sunmo, o si je okan ninu won,” gege bi o se salaye.
Ewe, Tems ti di obinrin olorin akoko to je omo Naijiria ti bilionu kan eniyan yoo gbo orin re ni oju awe Spotify.
O ri aseyori yii gba leyin ti o gbe orin re ti awon eniyan ti n reti, ‘Born In The Wild’ jade.