Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé-EFCC
Wọ́n ní Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé Ọrẹ Òtítọ́jù Àjọ tó ń gbógun ti ìwà ìjẹkújẹ lórílẹ̀ yìí, EFCC ti fi ipá mú gómìnà ìpínlẹ̀ Imo tẹ́lẹ̀, Sẹ́nétọ̀ Rochas Okorocha…
Read More »Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo
Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ Òtítọ́jù Igbákejì Ààrẹ orílẹ̀èdè yìí ,Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọsinbajo, ti sọ pé ọ̀kan pàtàkì lára àwọn ìpèníjà tó n kojú orílẹ̀èdè…
Read More »Agbébọn pa Họ́nọ́rébù Okechukwu Okoye ní ìpínlẹ̀ Anambra ,wọ́n tún gé orí rẹ̀ sọnù
Agbébọn pa Họ́nọ́rébù Okechukwu Okoye ní ìpínlẹ̀ Anambra ,wọ́n tún gé orí rẹ̀ sọnù Ọrẹ Òtítọ́jù Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Charles Chukwuma Soludo ti bu ẹnu àtẹ́ lu ikú aṣòfin Họ́nọ́rébù Okechukwu Okoye tí ọ̀pọ̀ mọ̀…
Read More »Ènìyàn márùn-ún wà láàyè, mẹ́ta ti kú nínú ilé tó dàwó ní ìpínlẹ̀ Eko— Àjọ LASEMA
Ènìyàn márùn-ún wà láàyè, mẹ́ta ti kú nínú ilé tó dàwó ní ìpínlẹ̀ Eko— Àjọ LASEMA Fẹ́mi Akínṣọlá Ògédé ẹni orí bá kó yọ nìkan ló móríbọ́ nínú-un làáṣìgbò àti pákáleke ayé. Àjọ tó ń mójútó…
Read More »Ẹ jẹ́ á fọwọ́ sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ẹni yòówù tó bá wọlé ibò abẹ́nú—-Ọṣinbajo
Ẹ jẹ́ á fọwọ́ sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ẹni yòówù tó bá wọlé ibò abẹ́nú—-Ọṣinbajo Ọrẹ Òtítọ́jù Ṣé wọ́n ní inú kò sí lààyè ò gbà.lgbákejì Ààrẹ Orílẹ̀ yìí , Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọṣinbajo, ti sọ pé, pẹ̀lú òǹkà…
Read More »Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí tó dárí ikọ̀ tó ja rédíò Ayefele lólè
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí tó dárí ikọ̀ tó ja rédíò Ayefele lólè Ọrẹ Òtítọ́jù Ọwọ́ iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Oyo ti tẹ afurasí kan, tó jẹ́ ọmọ ikọ̀ adigunjalè kan tó kọlu iléeṣẹ́ rédíò Yinka Ayefele, Fresh…
Read More »Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu
Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún ipò Ààrẹ lẹ́gbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC, àti adarí àpapọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú ọ̀hún, Aṣíwájú Bọla Ahmed Tinubu, ti rọ àwọn alátìlẹ́yìn…
Read More »Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ
Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìkan dárìn,bí kò ju bíntín, yóó fọwọ́ kọ́ nǹkan . Ó ti ń fojú hàn pé rúkèrúdò mí-ìn ti ń kànkù…
Read More »Agbébọn mọ̀ọ́mọ̀ pa àwọn aláwọ̀dúdú mẹ́wàá ní ilé itájà ní New York ni – Major
Agbébọn mọ̀ọ́mọ̀ pa àwọn aláwọ̀dúdú mẹ́wàá ní ilé itájà ní New York ni – Major Ọrẹ Òtítọ́jù À fi kí orí máa kóni yọ ninú ewu gbogbo,kó sì là wá lọ́wọ́ àwọn oníkòórìíra àti abínú ẹni.…
Read More »Íjọba ápápọ ni áwọn ti mu diẹ ninu ádéhun ọdun 2009 sẹ
Íjọba ápápọ ni áwọn ti mu diẹ ninu ádéhun ọdun 2009 sẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Ìpàdé tó wáyé láàrin ìjọba àpapọ̀ àti ẹgbẹ́ olùkọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga Fásitì, ASUU ní àná òde yìí ni ó forísánpọ́n lẹ́yìn…
Read More »Ìtumò̩ ò̩rò̩-orúko̩
Ìtumò̩ ò̩rò̩-orúko̩ E̩ jé̩ kí á ní ìmò̩ kún ìmò̩ wa ní ìkànnì Ô̩TÒ̩LÓRÌN. E̩ wo fídíò yí.
Read More »