Gadgets
no title
Tori Morata, Conte le Costa danu Fagidi-jaye agbaboolu Chelsea, Diegp Costa, ni won ti le danu bayii o. Adari Chelsea,…
Entertainment
Just Now
Tori Morata, Conte le Costa danu Fagidi-jaye agbaboolu Chelsea, Diegp Costa, ni won ti le danu bayii o. Adari Chelsea, Antonio Coasta ti so pe ‘bye bye’ fun Costa, tori Olorun ti bota buredi re lona…
no title
N ko ko iyan Olubadan kere – Ajimobi Bi igbese ti Gomina Ipinle Oyo, Senito Abiola Ajimobi, gbe nipa atunto loba-loba Ibadan se n ru opo eniyan loju, gomina naa ti so pe oun ko nii…
no title
Funke Akindele, Opeyemi Ayeola di omo ogoji odun nigba kan naa O ti wa f’oju han gedegbe bayii pe ose kan pere ni Funke Akindele-Bello fi ju Opeyemi Ayeola lo. Asiko kan naa ni irawo awon…
no title
Kin ni Olu Falaye fi se awon Fulani darandaran gan-an? Yoruba bo won ni a kii gbe’le eni ka f’orun ro. Sugbon ohun to ti n sele si okan lara awon agba Yoruba, Oloye Olu Falaye,…
no title
Paga! PSquare fo yangayanga: Peter ke gbajare pe Paul fe pa oun! Opin ti wa de si ajosepo awon gbajugbaja ibeji to da egbe osere PSquare sile o. Leyin opo odun ti won ti gbayi nile…
no title
A ko le ri iru Arsene Wenger mo – Alex Ferguson …ifeyinti Wenger si n mi papa isere titi Akinwale Taophic. E gbo na, kin ni awon ololufe re boolu fe ki Arsene Wenger o se…
no title
Lori adanwo Belgium, Neymar fi ohun gbogbo s’owo Olorun Agbaboolu omo Brazil, Neymar, si n se arokan tii fa ekun asun-undake lori bi egbe agbaboolu Belgium se le won kuro ni World Cup ni o. Omokunrin…