Má se jé̩wó̩ fún e̩nìkejì re̩ tí o bá yan àlè – Teju Babyface

Má se jé̩wó̩ fún e̩nìkejì re̩ tí o bá yan àlè – Teju Babyface

Mary Fágbohùn

Gbajumo aderinposonu Naijiria, Teju Oyelakin, ti a mo daadaa si Teju Babyface, ti se’kilo fun ololufe re lati ma se jewo fun enikeji won ti won ba yan ale.

Teju Babyface ni jijewo iru re je asise nla to buruku julo ninu igbeyawo.

Lasiko to n soro nipa atunbotan re, Teju ninu fonran kan lori ikanni ibanidore Instagram, tokasi sii pe jijewo ko se enikeji re ni anfaani kankan.

“Ma se jewo pe o yan ale: Ooto to ka ni laya ni! Gbogbo eeyan n so fun o pe ‘ma farapamo’ ti o ba yan ale. Koda won si Bibeli tumo lati tii leyin. Sugbon ki n so ko da monran: ijewo ni si Olorun, kii se oko tabi aya re.

“Ko si anfaani kan fun won (oko tabi aya re). Iwo lo ni gbogbo anfaani naa.